PRAISE MEDLEY - Ade Mike

Share on these Platforms
832
by DrealAdeMike, 3 months ago
6
PRAISE MEDLEY - Ade Mike

 Ade Mike returns with new single titled PRAISE MEDLEY.

It behoves that I should praise God for all He has doing and He’s yet doing in my life. I do have no story, testimony, success, victory, breakthrough and deliverance outside His knowledge and doing. The mighty one has continually done great things for me, so I must praise His name. This song, Praise Medly, comes out in Yoruba language basically, in the style of two renowned Yoruba Gospel Singers: Lanre Teriba (Atorise) and the late Rowland Olubukola Olomola (Baba Ara).
ADE MIKE – MEDLEY
Olorun Alagbara,
Oloore Ofe Nla
Alaanu Jojo
Onitoju Iyebiye
Alaabo ti Ntoni
Olufe Gbogbo Eniyan
Oluso to Daju
Olubukun ati Alagbawi
Olutunu,
Onike,
Elewa,
Ologo,
Oloore,
Apedahun,
Mimo Aileeri,
Eleda gbgbo eniyan…

Womi, Olorun lo fayo sii okan mi,
Womi ooo, Olorun lo ferin sii enu mi,
Iba ma sepe moni Jesu Loluwa oo,
Iba ma sepe moni Jesu Loolugbala,
Taleni naa to tu le fayo sii okan mi…

Baba modupe, Latori mi de ese mi,
Ise owo re ni,
Baba mo dupe.

Ogo, Iyin, Ola, folorun metaalokan,
Oba iyanu nla, (ye) to dara lopolopo,
Mo mo, o damiloju, ko sohun to o lese
All: Na you be God o, Olorun ajoboooooo,

Lead: Oya! Eba mi pe baba o, loruko to Nje – Ye
Backup: Baba O,
Ore O,
Alaabo,
Onimo,
Arabataribiti onimo to fiimo danilola funni lola,
Erujeje Oba-Oke Oba-Iye Alase Orunnnnn

Ye,
Bayi lawa nyin Jesu,
Ta Nyin Baba, A nyin Jesu,
Bayi lawa yin Jesu
Ao yiin lojojumo…

 

O semi lore agba-Iayanu,
Baba semi Loore agba-iyanu,
Ohun baba tabi iya ole se,
Olorun semi lore agba-iyanu…

MUSIC AND DANCE
Lead: Oya, Eje ka yin baba o, fun oore re
Lead: Baba Ayin o, eeeeh

Lead: Eje ka yin baba o, fun oore re
Lead: Ayin o, eeeeh

Lead: Olorun dada, Lolorun mi
Olorun dada, Lolorun mi,
Ose mi dada, Ohuwa dada simi,
Olorun dada, Lolorun mi

Lead: Eje ka yin baba o, fun oore re
backup: Baba Ayin o, eeeeh

Lead: Eje ka finu didun,
Yin Oluwa Olore,
Anu Re O wa titi,
Lododo daju daju
Lead: Mo ni ka yin Baba o, fun re re
backup: Baba Ayin o, eeeeh

Lead: Your Excellency Re o, Oba toto
Your Excellency Re o, Oba toto
Fun Ife Re ati Abo Re, Ti koyipo Pada,
Your Excellency Re o, Oba toto

Lead: Moni Keyin baba o, fun oore re
Lead: Baba Ayin o, eeeeh

Lead: Jesus conquered the world, and gave us victory,
Backup: Victory! Victory!! Halelluya!

Emi at’ ara ile mi,
Yio ma sin Oluwa wa;
Sugbon emi papa;
Yio f’ iwa at’ oro han,
Pe mo mo Oluwa t’ orun,
Mo nfokan toto sin.

Fun mi l’ ore- ofe toto,
Nje! Emi de lati jeri
’Yanu oruko Re,
Ti o gba mi l’owo egbe;
Ire eyi t’a mo l’ okan,
Ti gbogb’ ahon le so.

Lead: I just want to say, Baba o, E sheeeeeeee
Backup: I just want to say

ARA STYLE
Lead:
Baba o, Mo sope oooo eee!
Bomo ba monuro, Oye ko dupe lowo baba re o,

Iwo lo gbemi depo ti mowa yi,
Ogbon mi ko, kin de tu sagbara mi o

Ni diduro emi duro de Oluwa,
O deti simi, baba si gbo ekun mi,
O fami lowo soke latinu iho iparun wa,
Omu mi laya le, o si fese mi sori apata

Ima bami yin logo o, Olorun anu nla,
Ima bami pokiki ogo Olorun to fe mi

Backup: Yin! Yin!! Yin!!! Olorun Ogo o
Yin! Yin!! Yin!!! Olorun ife o
Ima bami a pokiki re, Olorun Iyanu

All instruments will play an interlude here…

Lead: A boro o gbo peee
Backu p: Oro mi gbope o, oro mi gbayo ooo
Backup: O-oo, Oooo-ooooo!
Baba ti funmi layo mo sori-ire
Oro mi dayo oooooo

Lead: Agbara mi koooooo o
Agbara jesu mo ni
Imo atoye mi kooooooo o
Anu Jesu momo ni o e
2 times
Backup: Awa yo gbe ga,
Awa yo yin baba o ee,
Awa yo yio Oruko re,
Olorun nla

 

Eyin Oba ogo, On ni Olorun
Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan
O wa pelu awon ero mimo l'ona
O si je imole won l'osan l'oru.

E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gb*ogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi.

E yin fun 'rapada ti gbogbo okan
E yin fun orisun imularada
Fun inu rere ati itoju re
Fun 'daniloju pe O ngbo adura,

E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi.

E yin fun idanwo bi okun ife,
T'o nso wa po moa won ohun orun
Fun 'gbagbo ti n|”segun , 'reti ti ki sa
Fun ile ogo t'O ti pese fun wa.
E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'

Facebook Comments
Comments | Add yours
  • No comments found

RELATED MUSIC

BELIEVER - SammieKeys [‏@sammiekeys]

Details
by sammiekeys 6 years ago
SAMUEL EHIKIOYA EDOROR better known as Sammie keys Who is a Music Producer, Song Writer and a Pianist Drops a new single titled "BELIEVER". the song i...
0 15 91
784 views

MADE IT - SammieKeys [‏@sammiekeys]

Details
by sammiekeys 6 years ago
MADE IT is an amazing new tune from Sammie keys.... It promises to keep you dancing and rejoicing for the level God has brought you from and where He...
2 5 86
1,107 views

More Videos

RELATED POSTS